[Lyrics] D.dat - Agba Ola

[Lyrics] D.dat - Agba Ola

 

1. Still don't have enough but never beg to feed

   Okun arà mí le,no sickness have waid me down
   In all Circumstances you're my God,you're my God
  Bi mì ranti àgbelèbú o,I feel blessed I got a grace

Rf: I brainstorm what it is I can call you,you that dwelleth in zion
  Mo ri pé Oba olá ni o jé , Olórun òrò

Chr: Ìwo làgbàlagbà Olá, Elérù ni yì
Ubangiji mi, mo dúpe è sé
Àgbàlagbà Olá, Ató faratì
Naraekelegi, Olórun òrò.

2. I've got a God the king of grace, the only one I see, whose hands are never too short Láti gbàmí
   I've got a God the king of wealth, the only one I see, who owns the whole world nd all in it.

Rf:I brainstorm what it is I can call you,you that dwelleth in zion
  Mo ri pé Oba olá ni o jé , Olórun òrò

Chr:Ìwo làgbàlagbà Olá, Elérù ni yì
Ubangiji mi, mo dúpe è sé
Àgbàlagbà Olá, Ató faratì
Naraekelegi, Olórun òrò.

Post a Comment

0 Comments
We want to hear from you all. Drop your comments below